Joshua 19:2-8

2Lára ìpín wọn ní:
Beerṣeba (tàbí Ṣeba), Molada,
3Hasari-Ṣuali, Bala, Esemu, 4Eltoladi, Betuli, Horma, 5Siklagi, Beti-Markaboti, Hasari Susa, 6Beti-Lebaoti àti Ṣarueli, ìlú wọn jẹ́ mẹ́tàlá àti ìletò wọn.
7Aini, Rimoni, Eteri àti Aṣani: Ìlú wọn jẹ́ mẹ́rin àti ìletò wọn: 8Àti gbogbo àwọn agbègbè ìlú wọ̀nyí títí dé Baalati-Beeri (Rama ní gúúsù).
Èyí ni ilẹ̀ ìní ẹ̀yà àwọn ọmọ Simeoni, agbo ilé, ní agbo ilé.
Copyright information for YorBMYO